"Ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation 2024"
intro
"<div lang="en" dir="ltr" class="mw-content-ltr">
[https://meta.wikimedia.org/wiki/Special:MyLanguage/Wikimedia_Foundation_elections/2024/Candidates Learn more about the candidates]
</div>
Ìdìbò yìí ó fi èsì àwọn olùdíje 4 tí a bá dìbò fún láti darapọ̀ mọ́ Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation.
* Ìdìbò yìí nlo ọ̀nà "Single Transferable Vote (STV)". [https://meta.wikimedia.org/wiki/Special:MyLanguage/Wikimedia_Foundation_elections/Single_Transferable_Vote È̩kúnrẹ́rẹ́ àlàyé wà lórí Meta-wiki lórí bíi aṣé nka irú ìdìbò yìí].
* Wàá rí àwọn àṣàyàn lórí ojú-ewé ìdìbò. Láti òkè ojú-ewé yìí, yan àwọn olùdíje ní bí o ṣe fẹ́ràn wọn sí, Lát'orí "Àṣàyàn 1" (ẹni tí o fẹ́ jùlọ) títí dé "Àṣàyàn 12" (ẹni tí o fẹ́ kẹ́yìn).
* O kò nílò láti dìbò fún olùdíje kọ̀ọ̀kan. O lè dákẹ́ yíyàn tí àwọn tí o fẹ́ràn bá ti parí. Bí àpẹẹrẹ, o lè yan olùdíje kàn, tàbí mẹ́rìn, tàbí gbogbo wọn.
* O lè ṣe àtúnṣe sí ìbò rẹẹ lákòkò ètò ìdìbò. Eléyìí yíò pa ìbò titẹ́lẹ̀ rẹ́. O lè ṣeléyì ní iye ìgbà tí ó bá wù ọ́."
jump-text
"Ìṣètò ìdìbò yìí ó wáyé lórí wiki ìṣọ̀kan. Jọ̀wọ́ tẹ bọ́tìnì ìsàlẹ̀ láti lọ síbẹ̀."
return-text
"Ojú-ewé fún ìdìbò Wikimedia Foundation 2024"
unqualified-error
"A tọrọ gáfárà, ṣùgbọ́n o kò sí lórí àtòjọ àwọn tó l'áṣẹ láti dìbò. Jọ̀wọ́ lọsí [https://meta.wikimedia.org/wiki/Special:MyLanguage/Wikimedia_Foundation_elections/2024/FAQ ojú-ewé ìrànlọ́wọ́ olùdìbò] fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọ̀rọ̀ lórí àṣe ìdìbò àti àlàyé lórí bí o ṣelè fọrúkọ s'órí àtòjọ olùdìbò tí o bá ní àṣẹ láti dìbò."